Ísíkẹ́lì 29:10 BMY

10 Nítorí náà, mo lòdì sí ọ àti sí àwọn odò rẹ, èmi yóò sì mú kí ilẹ Éjíbítì di píparun àti ahoro, pátapáta, láti Mígídólì lọ dé Ásíwánì, dé ààlà ilẹ Kúṣì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:10 ni o tọ