Ísíkẹ́lì 29:12 BMY

12 Èmi yóò sọ ilẹ Éjíbítì di ọ̀kan ní àárin àwọn ilẹ̀ tí ó di ahoro, fún ogójì ọdún, Èmi yóò sì fọ́n àwọn ara Éjíbítì ká sáàárin àwọn orílẹ̀ èdè, èmi yóò sì tú wọn ká sáàárin gbogbo ilẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:12 ni o tọ