Ísíkẹ́lì 29:3 BMY

3 Sọ̀rọ̀, kí ó sì wí pé: ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Èmi lòdì sí ọ, Fáráò ọba Éjíbítììwọ dírágónì ńlá inú òkun tí ó dùbúlẹ̀ síàárin àwọn odò ṣíṣàn rẹèyí tí ó sọ wí pé, “Tèmi ni odò Náílì;èmi ni ó sì ṣe é fún ara mi.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:3 ni o tọ