Ísíkẹ́lì 29:8 BMY

8 “ ‘Nítorí náà, èyí yìí ní Olúwa Ọlọ́run wí: kéyèsí i Èmi yóò mú idà kan wá sórí rẹ tí yóò sì gé ènìyàn àti ẹran kúrò nínú rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 29

Wo Ísíkẹ́lì 29:8 ni o tọ