Ísíkẹ́lì 3:12 BMY

12 Nígbà náà ni Ẹ̀mí gbé mi sókè, mo sì gbọ́ ohùn ìró ńlá lẹ́yìn mi-tó sọ pé, kí a gbé ògo Olúwa ga láti ibùgbé rẹ̀ wá!

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:12 ni o tọ