Ísíkẹ́lì 3:15 BMY

15 Nígbà náà ni mo lọ sí etí odò Kébárì níbi tí àwọn ìgbèkùn ń gbé ni Teli-Ábíbì. Níbẹ̀ níbi tí wọ́n ń gbé, mo jókòó láàrin wọn pẹ̀lú ìyànu, fún ọjọ́ méje.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:15 ni o tọ