Ísíkẹ́lì 3:22 BMY

22 Ọwọ́ Olúwa wà lára mi níbẹ̀, ó sì wí fún mi pé, “Dìde, lọ sí ibi tí ó tẹ́jú, èmi yóò sì bá ọ sọ̀rọ̀ níbẹ̀.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:22 ni o tọ