Ísíkẹ́lì 31:13 BMY

13 Gbogbo àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run ṣe àtìpó ni orí igi tí ó subú lulẹ̀ náà, gbogbo àwọn ẹranko ìgbẹ́ wà ní àárin ẹ̀ka rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 31

Wo Ísíkẹ́lì 31:13 ni o tọ