Ísíkẹ́lì 31:4 BMY

4 Omi mú un dàgbà sókè:orísun omi tí ó jìnlẹ̀ mú kí o dàgbà sókè;àwọn odo rẹ̀ ń sàn yí ìdí rẹ̀ ká,ó sì rán ìṣàn omi rẹ̀ sí gbogbo igi orí pápá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 31

Wo Ísíkẹ́lì 31:4 ni o tọ