Ísíkẹ́lì 31:8 BMY

8 Àwọn òpépé igi nínú ọgbà Ọlọ́runkò lè è bá a dọ́gba,tàbí kí àwọn igi firiṣe déédé pẹ̀lú ẹ̀ka rẹ̀,tàbí kí a fi igi títẹ́ rẹrẹ wé ẹ̀ka rẹ̀,kò sí igi nínú ọgbà Ọlọ́runtí ẹwà rẹ̀ ṣe déédé pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 31

Wo Ísíkẹ́lì 31:8 ni o tọ