Ísíkẹ́lì 32:16 BMY

16 “Èyí yìí ni ẹkún tí a óò sun fún un. Àwọn ọmọbìnrin orílẹ̀ èdè yóò sun ún; nítorí Éjíbítì àti gbogbo ìjọ rẹ, wọn yóò sun ún, ní Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:16 ni o tọ