Ísíkẹ́lì 32:26 BMY

26 “Méṣékì àti Túbálì wà níbẹ̀, pẹ̀lú gbogbo ìjọ wọn yí isà òkú wọn ká. Gbogbo wọn jẹ́ aláìkọlà, wọ́n fi idà pa wọ́n nítorí ẹ̀rù ti wọn tàn ká ilẹ̀ alààyè.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:26 ni o tọ