Ísíkẹ́lì 32:29 BMY

29 “Édómù wà níbẹ̀, àwọn Ọba rẹ̀ àti gbogbo ọmọbìnrin Ọba; bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ní agbára, a tẹ́ wọn pẹ̀lú àwọn tí a fi idà pa. Wọn dùbúlẹ̀ pẹ̀lú aláìkọlà, pẹ̀lú àwọn ti o lọ sínú kòtò.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:29 ni o tọ