Ísíkẹ́lì 33:26 BMY

26 Ẹ̀yin gbẹ́kẹ̀lé idà yín, ẹ̀yin ṣe nǹkan ìríra, ẹnì kọ̀ọ̀kan nínú yín baa obìnrin aládúgbò rẹ̀ jẹ́. Ẹ̀yin yóò ha gba ilẹ̀ náà?’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:26 ni o tọ