Ísíkẹ́lì 33:28 BMY

28 Èmi yóò mú kí ilẹ náà di ahoro, agbára ìgbéraga rẹ̀ yóò sì di ahoro kí ẹnikẹ́ni má ṣe ré wọn kọjá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:28 ni o tọ