6 Ṣùgbọ́n bí alóre bá rí idà ti o ń bọ̀, tí kò sì fọn ìpè láti ki àwọn ènìyàn nílọ̀, tí idà náà wá, tí ó sì gba ẹ̀mí ọ̀kan nínú wọn, a óò mú ọkùnrin náà lọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, ṣùgbọ́n èmi yóò bèèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀.’
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33
Wo Ísíkẹ́lì 33:6 ni o tọ