Ísíkẹ́lì 34:17 BMY

17 “ ‘Ní tìrẹ, agbo ẹran mi, èyí yìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Èmi yóò ṣe ìdájọ́ láàrin àgùntàn kan àti òmíràn, àti láàrin àgbò àti ewúrẹ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:17 ni o tọ