Ísíkẹ́lì 34:19 BMY

19 Ṣé dandan ni kí agbo ẹran mi jẹ́ koríko tí ẹ ti tẹ̀ mọ́lẹ̀, kí wọn sì mú omi tí wọ́n ti fi ẹsẹ̀ wọn sọ di ẹrẹ̀?

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:19 ni o tọ