Ísíkẹ́lì 34:22 BMY

22 Èmi yóò gba agbo ẹran mi là, a kì yóò sì kò wọ́n tì mọ́. Èmi yóò ṣe ìdájọ́ láàrin àgùntàn kan àti òmíràn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:22 ni o tọ