Ísíkẹ́lì 34:24 BMY

24 Èmi Olúwa yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn, ìránṣẹ́ mi Dáfídì yóò jẹ́ ọmọ aládé láàárin wọn. Èmi Olúwa ní o sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:24 ni o tọ