Ísíkẹ́lì 34:29 BMY

29 Èmi yóò pèsè ilẹ̀ ti o ní oríyìn fún èso rẹ̀ fún wọn, wọn kì yóò sì jìyà nípasẹ̀ ìyàn mọ́ ni ilẹ̀ náà tàbí ru ẹ̀gàn àwọn orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:29 ni o tọ