Ísíkẹ́lì 34:3 BMY

3 Ìwọ jẹ wàrà. O sì wọ aṣọ olówùú sí ara rẹ, o sì ń pa ẹran tí ó wù ọ́, ṣùgbọ́n ìwọ kò tọ́jú agbo ẹran.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:3 ni o tọ