Ísíkẹ́lì 35:3 BMY

3 Kí o sì sọ wí pé: ‘Èyí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Èmí lòdì sí ọ, òkè Séírì, Èmi yóò sì na ọwọ́ mi síta ní ìlòdì sí ọ, èmi yóò sì mú kí o di ahoro.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 35

Wo Ísíkẹ́lì 35:3 ni o tọ