Ísíkẹ́lì 35:6 BMY

6 nítorí náà bi mo ti wà láàyè, ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, èmi yóò fi ọ kalẹ̀ fún ìtàjẹ̀ sílẹ̀, ìtàjẹ̀ sílẹ̀ yóò sì lépa rẹ. Níwọ̀n ìgbà tí ìwọ kò ti korìíra ìtàjẹ̀-sílẹ̀, ìtàjẹ̀-sílẹ̀ yóò sì lépa rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 35

Wo Ísíkẹ́lì 35:6 ni o tọ