Ísíkẹ́lì 36:10 BMY

10 èmi yóò sì sọ iye àwọn ènìyàn di púpọ̀ nínú rẹ àti gbogbo ilé Ísírẹ́lì. Àwọn ìlú yóò di ibùgbé, a óò sì tún àwọn ibi ìparun kọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:10 ni o tọ