Ísíkẹ́lì 36:20 BMY

20 Gbogbo ibi tí wọ́n lọ ní àárin àwọn orílẹ̀ èdè ni wọn ti sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́, nítorí tí a sọ nípa wọn pé, ‘Ìwọ̀nyí ni àwọn ènìyàn Olúwa, síbẹ̀ wọn ní láti fí ilẹ̀ náà sílẹ̀.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:20 ni o tọ