Ísíkẹ́lì 36:24 BMY

24 “ ‘Nítorí èmi yóò mú yín jáde kúrò ni àwọn orílẹ̀ èdè náà; Èmi yóò ṣà yín jọ kúrò ní gbogbo àwọn ìlú náà; Èmi yóò sì mú yín padà sí ilẹ̀ ẹ̀yin tìkarayín.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:24 ni o tọ