Ísíkẹ́lì 36:27 BMY

27 Èmi yóò fi ẹ̀mí mi sínú yín, èmi yóò sì mú ki ẹ tẹ̀lé àṣẹ mi, kí ẹ sì fiyèsí àti pa òfin mi mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:27 ni o tọ