Ísíkẹ́lì 36:31 BMY

31 Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò rántí àwọn ọ̀nà búburú àti àwọn ìwà ìkà yín, ẹ̀yin yóò sì korìíra ara yín fún ẹ̀ṣẹ̀ yín, ìwà tí kò bójúmu.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:31 ni o tọ