Ísíkẹ́lì 36:38 BMY

38 Kí ó pọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ bí ọ̀wọ́ ẹran fún ìrúbọ ní Jérúsálẹ́mù ní àsìkò àjọ. Ìlú ti a parun yóò wá kún fún agbo àwọn ènìyàn. Nígbà náà ni wọn yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 36

Wo Ísíkẹ́lì 36:38 ni o tọ