8 Mo wò ó, ìṣan ara àti ẹran ara farahàn lára wọn, awọ ara sì bò wọ́n, ṣùgbọ́n kò sí èémí nínú wọn.
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37
Wo Ísíkẹ́lì 37:8 ni o tọ