Ísíkẹ́lì 38:11 BMY

11 Ìwọ yóò wí pé, “Èmi yóò gbé Ogun ti ilẹ̀ àwọn tí a kò fi odi yíká: Èmi yóò gbé ogun ti àwọn ènìyàn àlàáfíà tí a kò furasí-gbogbo wọn ń gbé ní àìsí odi, ní àìsí ẹnu ọ̀nà òde àti àsígbà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38

Wo Ísíkẹ́lì 38:11 ni o tọ