21 Èmi yóò fa idà yọ ni ìlòdì sí Gógì ní orí gbogbo àwọn òkè gíga mi ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí. Idà gbogbo ènìyàn yóò lòdì sí arákùnrin rẹ̀.
Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 38
Wo Ísíkẹ́lì 38:21 ni o tọ