Ísíkẹ́lì 39:19 BMY

19 Níbi ìrúbọ tí mo ń múra kalẹ̀ fún yín, ẹ̀yin yóò jẹ ọ̀rá títí ẹ̀yin yóò fi jẹ àjẹkì, ẹ̀yin yóò sì mú ẹ̀jẹ̀ títí ẹ̀yin yóò fi yó.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:19 ni o tọ