Ísíkẹ́lì 39:26 BMY

26 Wọn yóò gbàgbé ìtìjú wọn àti gbogbo àìsòdodo tí wọ́n fihàn sí mi nígbà tí wọn ń gbé ni àìléwu ni ilẹ̀ wọn níbi tí kò ti sí ẹnìkẹ́ni láti dẹ́rù bà wọ́n.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 39

Wo Ísíkẹ́lì 39:26 ni o tọ