Ísíkẹ́lì 4:1 BMY

1 “Nísinsìnyìí, Ìwọ ọmọ ènìyàn, mú amọ̀ ṣíṣù kan, gbé e sí iwájú rẹ, kí o sì ya àwòrán Jérúsálẹ́mù sí orí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:1 ni o tọ