Ísíkẹ́lì 4:13 BMY

13 Olúwa sọ pé, “Báyìí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò jẹ oúnjẹ àìmọ́ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè tí èmi yóò lé wọn lọ.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:13 ni o tọ