Ísíkẹ́lì 4:16 BMY

16 Ó sì tún sọ fún mi pé: “Ọmọ ènìyàn, èmi yóò dáwọ́ ìpèsè oúnjẹ dúró ní Jérúsálẹ́mù. Ní pípín ni àwọn ènìyàn yóò máa pín oúnjẹ́ jẹ pẹ̀lú ìfọ̀kansọ́nà bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni wọn yóò máa mu omi pẹ̀lú ìdààmú,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:16 ni o tọ