Ísíkẹ́lì 4:3 BMY

3 Kí o sì fi páànù irin kan ṣe ògiri láàrin rẹ̀ àti ìlú yìí, dojú kọ ọ́, kí o sì gbógun tì í. Èyí yóò jẹ́ àmì fún ilé Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:3 ni o tọ