Ísíkẹ́lì 40:37 BMY

37 Àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà rẹ̀ dojúkọ àgbàlá ìta; àwọn igi ọ̀pẹ ṣe ọ̀sọ́ sí àwọn àtẹ́rígbà rẹ̀ ni ẹ̀gbẹ́ méjèèjì, àtẹ̀gùn mẹ́jọ ní ó so mọ́ ọn lókè.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:37 ni o tọ