Ísíkẹ́lì 41:11 BMY

11 Àwọn ojú ọ̀nà àbáwọlé wá sí àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́, ọ̀kan ní àríwá àti èkejì ní gúsù, ojú ọ̀nà ni ìsàlẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀wọ́ márùn-ún ní fífẹ̀ yípo rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 41

Wo Ísíkẹ́lì 41:11 ni o tọ