Ísíkẹ́lì 41:22 BMY

22 Pẹpẹ ìrúbọ kan tí a fi igi ṣe wà, gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjì, àwọn igun rẹ̀, ìsàlẹ̀ rẹ̀ àti ògiri rẹ́ jẹ́ igi. Ọkùnrin náà sọ fún mi pé, “Èyí yìí ní tẹ́ḿpìlì tí ó wà ní iwájú Olúwa.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 41

Wo Ísíkẹ́lì 41:22 ni o tọ