Ísíkẹ́lì 41:4 BMY

4 O sì wọn gígùn inú yàrá ibi mímọ́; o sì jẹ ogún ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́ títí dé ìparí ìta ibi mímọ́. O sì sọ fún mi pé, “Èyí yìí ni ibi mímọ́ jùlọ.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 41

Wo Ísíkẹ́lì 41:4 ni o tọ