Ísíkẹ́lì 42:10 BMY

10 Ní ìhà gúsù lọ sí ìbú ògiri ìta ilé ìdájọ́ tí o ṣe déédé pẹ̀lú àgbàlá ilé Ọlọ́run, ní òdìkejì ògiri ìta ni àwọn yàrá náà wà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 42

Wo Ísíkẹ́lì 42:10 ni o tọ