Ísíkẹ́lì 43:22 BMY

22 “Ní ọjọ́ kejì ìwọ yóò fi ewúrẹ́, òbúkọ aláìlábàwọ́n fún ẹbọ ẹsẹ, a sì gbọdọ̀ sọ pẹpẹ di mímọ́ gẹ́gẹ́ bí a ti sọ́ di mímọ́ pẹ̀lú akọ màlúù.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:22 ni o tọ