Ísíkẹ́lì 43:9 BMY

9 Nísinsin yìí jẹ́ kí wọn mú ìwà àgbérè wọn àti àwọn ère aláìlẹ́mìí àwọn Ọba wọn kúrò ni iwájú mi, èmi yóò sì gbé àárin wọn láéláé.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 43

Wo Ísíkẹ́lì 43:9 ni o tọ