Ísíkẹ́lì 44:13 BMY

13 Wọn kò gbọdọ̀ súnmọ́ ọ̀dọ̀ mi láti se ìránṣẹ́ fún mi, gẹ́gẹ́ bí àlùfáà tàbí súnmọ́ ìkankan nínú àwọn ohun mímọ́ mi tàbí ẹbọ mi mímọ́ jùlọ; wọn gbọdọ̀ gba ìtìjú ìwà ìríra wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:13 ni o tọ