Ísíkẹ́lì 44:16 BMY

16 Àwọn nìkan ni ó gbọdọ̀ wọ ibi mímọ́ mi; àwọn nìkan ní o gbọdọ̀ sùnmọ́ tábìlì mi láti ṣe ìránṣẹ́ ni iwájú mi, ki wọn sì ṣe iṣẹ́ ìsìn mi.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:16 ni o tọ