Ísíkẹ́lì 44:18 BMY

18 Wọ́n ní láti dé fìlà ọ̀gbọ̀ sí orí wọn àti àwọ̀tẹ́lẹ̀ ọ̀gbọ̀ sí ìdí wọn. Wọn kò gbọdọ̀ wọ ohunkóhun tí yóò mú wọn làágùn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:18 ni o tọ