Ísíkẹ́lì 44:23 BMY

23 Wọn ní láti fi ìyàtọ̀ tí ó wà nínú mímọ́ àti aláìmọ́ kọ́ àwọn ènìyàn mi, kí wọn sì fi bi wọn yóò ṣe dá aláìmọ́ mọ̀ yàtọ̀ sí mímọ́ hàn wọ́n.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:23 ni o tọ